1
/
de
1
Aisagabagebe: Eni, Ogún PDF
Aisagabagebe: Eni, Ogún PDF
2 reviews
Prix habituel
$9.99 USD
Prix habituel
Prix promotionnel
$9.99 USD
Prix unitaire
/
par
Taxes incluses.
Frais d'expédition calculés à l'étape de paiement.
Impossible de charger la disponibilité du service de retrait
Ka. Loye. Ṣe.
Share
T
Taibat Ní ayé tá a wà yìí, àwọn ọmọ kéékèèké máa ń kọ́ “bí a ṣe ń kà” ṣùgbọ́n a kì í kọ́ wọn “ìdí tí kíkà ṣe ṣe pàtàkì.Aisagabagebe mú àmọ̀ràn tuntun wá. Ìwé yìí ko kọ́ nọ́mbà nìkan, ó kọ́ àwọn ìlànà ìwà rere, lílo ohun ti a le foju ri láti ṣàlàyé ohun tí kò le fojuri bí ìfẹ́ àti aisagabagebe. Ìwé yìí ní ẹ̀kọ́ tó jinlẹ̀. Ó lè ràn òbí lọ́wọ́ láti tọ́ ọmọ rẹ̀ sójú ọ̀nà nípasẹ̀ àpẹẹrẹ ojoojúmọ́. Nípasẹ̀ kíkà, ọmọ náà máa kọ́ pé ìfẹ́ kì í ṣe ìfọ́kànsìn àti ìfẹ nìkan, ṣùgbọ́n pé ó tún jẹ́ ìdájọ́, pínpín, àti ìrònú fún àwọn ẹlòmíràn.
“Ohun-afiṣere méjì wà. Mo fẹ́ kan. Ìwọ náà fẹ́ kan. Gbogbo wa ní kan'