Skip to product information
1 of 1

Aisagabagebe: Eni, Ogún PDF

Aisagabagebe: Eni, Ogún PDF

Regular price $9.99 USD
Regular price Sale price $9.99 USD
Sale Sold out
Taxes included.

Ka. Loye. Ṣe.

View full details

Customer Reviews

Based on 2 reviews
50%
(1)
50%
(1)
0%
(0)
0%
(0)
0%
(0)
T
Taibat
Kíkọ́ Òdodo Nípasẹ̀ Kíkà Onka, teaching fairness through numbers

Ní ayé tá a wà yìí, àwọn ọmọ kéékèèké máa ń kọ́ “bí a ṣe ń kà” ṣùgbọ́n a kì í kọ́ wọn “ìdí tí kíkà ṣe ṣe pàtàkì.Aisagabagebe mú àmọ̀ràn tuntun wá. Ìwé yìí ko kọ́ nọ́mbà nìkan, ó kọ́ àwọn ìlànà ìwà rere, lílo ohun ti a le foju ri láti ṣàlàyé ohun tí kò le fojuri bí ìfẹ́ àti aisagabagebe. Ìwé yìí ní ẹ̀kọ́ tó jinlẹ̀. Ó lè ràn òbí lọ́wọ́ láti tọ́ ọmọ rẹ̀ sójú ọ̀nà nípasẹ̀ àpẹẹrẹ ojoojúmọ́. Nípasẹ̀ kíkà, ọmọ náà máa kọ́ pé ìfẹ́ kì í ṣe ìfọ́kànsìn àti ìfẹ nìkan, ṣùgbọ́n pé ó tún jẹ́ ìdájọ́, pínpín, àti ìrònú fún àwọn ẹlòmíràn.
“Ohun-afiṣere méjì wà. Mo fẹ́ kan. Ìwọ náà fẹ́ kan. Gbogbo wa ní kan'

L
Lola
ṣìṣàlàyé Àkọlé yìí rọrùn, ó sì dá lórí ìtọ́sọ́nà nípa lilo onka

Ìwé yìí kọ́ àwọn ọmọ kéékèèké bí wọ́n ṣe lè ló àwọn nọ́mbà tayọ kíkà. Ó ràn wọ́n lọ́wọ́ nípa aiṣagabagebe ninu ìmúlò onka nígbà tí wọ́n bá nilati sọ kókó ọ̀rọ̀ ìdájọ́ àti ìdáhùn. atẹkọ monifẹre wulo fun mi lati kọ ifiransẹ yi.